Matsuo Bashō

Àdàkọ:Contains Japanese textMatsuo Bashō (松尾 芭蕉?, 1644 – November 28, 1694), abiso Matsuo Kinsaku (松尾 金作?), nigbana bi Matsuo Chūemon Munafusa (松尾 忠右衛門 宗房?)[1][2], je akoewi togbajumojulo ni igba Edo ni Japan. Nigba aye re, Bashō gbajumo fun awon ise re ninu iru collaborative haikai no renga alajobarasepo; loni, leyin opo orundun awiso lori ise re, o gbajumo bi oga ninu haiku soki ati kedere. Awon ewi re gbajumo kakiri aye.

Matsuo Bashō
Láàrin orúkọ ará Japan yìí, orúkọ ìdílé ni Matsuo.
Matsuo Bashō (松尾 芭蕉)
Pen nameSōbō (宗房)
Tōsē (桃青)
Bashō (芭蕉)
Iṣẹ́Poet
Ọmọ orílẹ̀-èdèJapanese
Notable worksOku no Hosomichi



Itokasi