Parisi

Parisi (Faransé: Paris) jẹ́ olúìlú orílẹ̀-èdè Fránsì àti ìlú tó tobijulọ nibẹ. Àwọn ibi tó lajú níbẹ̀ gba ìlẹ̀ tó tóbi tó 105.40 km² pẹ̀lú olùgbélú 2,220,445 ní ìkànìyàn ọdún 2014.

Parisi

Paris
The Eiffel Tower (foreground) and the skyscrapers of Paris's suburban La Défense business district (background).
The Eiffel Tower (foreground) and the skyscrapers of Paris's suburban La Défense business district (background).
Flag of Parisi
Flag
Location of Parisi
Population
2,203,817
Websiteparis.fr