Tanzania
Tànsáníà tabi Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìṣọ̀kan ilẹ̀ Tànsáníà (pípè /ˌtænzəˈniːə/; Swahili: Jamhuri ya Muungano wa Tanzania)[11] je orile-ede ni Ilaoorun Afrika to ni bode mo Kenya ati Uganda ni ariwa, Rwanda, Burundi ati orile-ede Olominira Toseluarailu ile Kongo ni iwoorun, ati Zambia, Malawi ati Mozambique ni guusu. Awon bode Tansania ni ilaorun ja si Okun India.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìṣọ̀kan ilẹ̀ Tànsáníà United Republic of Tanzania Jamhuri ya Muungano wa Tanzania (Swahili) | |
---|---|
Motto: "Uhuru na Umoja" (Swahili) "Freedom and Unity" | |
Olùìlú | Dodoma (de jure) |
Ìlú tótóbijùlọ | Dar es Salaam |
Official Language | |
National Language | Swahili[1] |
Orúkọ aráàlú |
|
Ìjọba | Unitary dominant party presidential constitutional republic[2][3][4] |
Samia Hassan Suluhu | |
• Vice-President | Vacant |
• Prime Minister | Kassim Majaliwa |
• Speaker | Job Ndugai |
• Chief Justice | Ibrahim Hamis Juma |
Aṣòfin | National Assembly |
Independence from the United Kingdom | |
9 December 1961 | |
• Unguja and Pemba | 10 December 1963 |
• Merger | 26 April 1964 |
• Current constitution | 25 April 1977 |
Ìtóbi | |
• Total | 947,303 km2 (365,756 sq mi) (31st) |
• Omi (%) | 6.4[5] |
Alábùgbé | |
• Àdàkọ:UN Population estimate | Àdàkọ:UN PopulationÀdàkọ:UN Population (25th) |
• 2012 census | 44,928,923[6] |
• Ìdìmọ́ra | 47.5/km2 (123.0/sq mi) |
GDP (PPP) | 2019 estimate |
• Total | $186.060 billion |
• Per capita | $3,574[7] |
GDP (nominal) | 2019 estimate |
• Total | $61.032 billion |
• Per capita | $1,172[7] |
Gini (2012) | 37.8[8] medium |
HDI (2018) | ▲ 0.528[9] low · 159th |
Owóníná | Tanzanian shilling (TZS) |
Ibi àkókò | UTC+3 (EAT) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | left |
Àmì tẹlifóònù | +255[note 1] |
ISO 3166 code | TZ |
Internet TLD | .tz |
Awon agbegbe
Awon agbegbe Tanzania niwonyi:Arusha · Dar es Salaam · Dodoma · Iringa · Kagera · Kigoma · Kilimanjaro · Lindi · Manyara · Mara · Mbeya · Morogoro · Mtwara · Mwanza · Pemba North · Pemba South · Pwani · Rukwa · Ruvuma · Shinyanga · Singida · Tabora · Tanga · Zanzibar Central/South · Zanzibar North · Zanzibar Urban/West
Àwọn ìtọ́kasí
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "note", but no corresponding <references group="note"/>
tag was found