23 February 2008(2008-02-23) (ọmọ ọdún 57) Zaplana, Slovenia
Ẹgbẹ́ olóṣèlú
Movement for Justice and Development (2006–2008)
Other political affiliations
League of Communists (Before 1990) Liberal Democracy (1990–2006)
(Àwọn) olólùfẹ́
Majda Drnovšek (Divorced 1980)
Alma mater
University of Ljubljana University of Maribor
Janez Drnovsek (May 17, 1950 – February 23, 2008) A bí ní ọdún 1950. Ó jẹ́ olóòtú ìjọba Slovenia ní 1992 sí 2002. Lẹ́yìn èyí ni ó di àrẹ ilẹ̀ náà. Ní ọdún 1999 ni àìsàn kan ń bá a jà ní kíndìnrín. Ẹ̀kọ́ nípa ‘economics’ ni ó kà. Ó sì di ọmọ ilẹ́ asòfin ilẹ̀ slovenia ni ọdún 1986. Iṣẹ́ ribiribi ni ó ṣe láàrin ọdún mẹ́wàá tí ó fi ṣe olóòtú ìjọba. Ó jẹ́ kí ilẹ̀r eẹ̀ dara pọ̀ mọ́ European union àti NATO ní 2004. Oṣù kéjìlá ọdún 2007 bí ó fi ipò àrẹ ilẹ̀ slovenia sílẹ̀. Ó kú nígbà tí ó di ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógọ́ta.