Robert Mugabe

Robert Gabriel Mugabe (Pípè ní èdè Shona: [muɡaɓe], English: /mʊˈɡɑːbeɪ/ moo-GAH-bay; ojoibi 21 Oṣù Kejì 1924 - 6 Oṣù Kẹ̀sán 2019) jẹ́ ààrẹ orílẹ̀ èdè Zimbabwe tẹ́lè. Ó jẹ́ ìkan lára àwọn ajàgbòmìnira fún orílẹ̀ èdè Zimbabwe. Ó jẹ́ alákóso orílẹ̀ èdè yí láti ọdún 1980 sí 1987 kí ó tó di ààrẹ.[1]

Robert Mugabe
Ààrẹ orílẹ̀ èdè Zimbabwe tẹ́lè.
In office
31 December 1987 – 21 November 2017
Alákóso ÀgbàMorgan Tsvangirai
Vice PresidentSimon Muzenda
Joseph Msika
Joice Mujuru
John Nkomo
AsíwájúCanaan Banana
Arọ́pòEmmerson Mnangagwa
Prime Minister of Zimbabwe
In office
18 April 1980 – 31 December 1987
ÀàrẹCanaan Banana
AsíwájúAbel Muzorewa (Zimbabwe Rhodesia)
Arọ́pòPost abolished Revived 2009: Morgan Tsvangirai
Secretary-General of the Non-Aligned Movement
In office
6 September 1986 – 7 September 1989
AsíwájúZail Singh
Arọ́pòJanez Drnovsek
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1924-02-21)21 Oṣù Kejì 1924
Kutama, Salisbury, Southern Rhodesia
Aláìsí6 Oṣù Kẹ̀sán 2019 (ọmọ ọdún 95)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúZANU-PF (1987-2017)
ZANU (1963–1987)
ZAPU (1961–1963)
(Àwọn) olólùfẹ́Sally Hayfron (deceased)
Grace Marufu
Alma materUniversity of Fort Hare
University of Oxford
University of South Africa
University of London
Signature

Àwọn ìtọ́kasí