Àrùn gágá

Àrùn òtútù tabi òtútù (flu) jẹ́ àrùn àkóràn láàrín awon òlóngo (ẹyẹ, àdìrẹ) àti àwọn àfòmúbọmó tí èràn RNA ẹbí Orthomyxoviridae ń fà.[1] Láàrín àwọn ènìyàn ìbá ń fa òtútù (ìgbónạ́-ara), ẹ̀dùn lọ́rùn, ẹ̀dùn iṣan, ìforí kíkankíkan, ikọ̀, àìlágbára àti ìrora.[2][3]

Àrùn gágá
Àrùn gágáInfluenza virus, magnified approximately 100,000 times
Àrùn gágáInfluenza virus, magnified approximately 100,000 times
Influenza virus, magnified approximately 100,000 times
Ìpínsọ́wọ̀ àti àwọn òkunfà ìta
ICD/CIM-10J10., J11. J10., J11.
ICD/CIM-9487 487
OMIM614680
DiseasesDB6791
MedlinePlus000080

Àwọn ìtọ́kasí

Ẹ tún wo

Àwọn ìjápọ̀ lóde