Àsìá

Àsíá jẹ́ aṣọ pélébé tí ó ni àwọn àpẹẹrẹ àrànbara tí ó dúró fún àmì, amí tàbí èṣọ́. Ìwúlò kan pàtàkì tí ó ni ni wípé wọ́n a maa lòó gẹ́gẹ́ bí àmi orílẹ̀ èdè.[1][2]

Àsìá ilẹ̀ Nigeria

Àwọn ìtọ́kasí