Àwọn Òpó Márùún Ìmàle
Àwọn Òpó Márùún Islam (Arabic: أركان الإسلام) ni a n pe awon ojuse marun to se dandan fun gbogbo musulumi. Awon ojuse wonyi ni:
- Shahada (ijẹrisi igbagbo ninu ọkan Olorun ati pe anọbi muhammad ẹrusin ati ojiṣẹ rẹ ni nṣe),
- Irun (adura ojoojumo fún àwọn ada yanrí wakati máàrún),
- Itọ ọrẹ anu Zakat jẹ ọrọyàn lẹ kan lọdun fún gbogbo musulumi ti o ba ní owo nipa mọ Ka odindin ọdún tí bukata kan ko kọlù. Ida kàn ogójì ni yi o fi tọ ọrẹ (ọpọlọpọ Musulumi ma n saba yọ zakat wọn losu Ramadan nitori lada to pọ ninu oṣu náà)
- Awe osu Ramadan jẹ awẹ ọrọ yan nigba osu Ramadan fún gbogbo musulumi, ati
- Haji (irinajo lo si Mekka, ibi ti Masjid al-Haram (Mosalasi Mimo) wa, to je mosalasi to gbajumo julo ninu Imale).
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Wikipedia:Nípa WikipediaOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWikipedia:Èbúté ÀwùjọÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíPàtàkì:SearchWikipediaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Èdè YorùbáÀṣà YorùbáÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgBobriskyWikipedia:Abẹ́ igiPraguePàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunLinda IkejiWikipedia:Àyọkà pàtàkìPàtàkì:ÀwọnÀfikúnMiMọ́remí ÁjàṣoroFáwẹ̀lì YorùbáPornhubOwe YorubaÀmìọ̀rọ̀ QREre idarayaISO 8601Ògún LákáayéOrúkọ YorùbáÈdè Gẹ̀ẹ́sìIṣẹ́ Àgbẹ̀OSI modelIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanẸ̀ka:Àwọn Àyọkà pẹ̀lú ìjúwe ṣókíÌgbéyàwóHTMLKikan Jesu mo igi agbelebuÀrokòISBN