Èbúté:Ìmọ̀ ìṣirò

OJÚ EWE IMO ISIRO

Ìmọ̀ Ìṣirò jẹ́ èyí t'on jẹ mo nipa ọ̀pọ̀iye (quantity), nipa òpó (structure), nipa iyipada (change) ati nipa ààyè (space). Idagbasoke imo Isiro wa nipa lilo àfòyemọ̀ọ́ (abstraction) ati Ọgbọ́n ìrọ̀nú, pelu onka, isesiro, wíwọ̀n ati nipa fi fi eto s'agbeyewo bi awon ohun se ri (shapes) ati bi won se n gbera (motion). Eyi ni awon Onimo Isiro n gbeyewo, ero won ni lati wa aba tuntun, ki won o si fi ootọ́ re mulẹ̀ pelu itumo yekeyeke.

A n lo Imo Isiro ka kiri agbaye ni opolopo ona ninu Imo Sayensi, Imo Ise Ero, Imo Iwosan, ati Imo Oro Okowo. Bi a se n lo imo Isiro bo si apa eyi ti a n pe ni Iwulo Imo Isiro (Applied Mathematics). Apa keji Imo Isiro ni a mo si Imo Isiro Ogidi. Eyi je mo eko imo isiro to ko ti ni ilo kankan bo tileje pe o se se ki a wa ilo fun ni eyinwa ola.

Awon Orisirisi Nomba ti o wa
  • Nọ́mbà Àkọ́kọ́
  • Nọ́mbà Tódọ́gba
  • Nọ́mbà Tósẹ́kù
  • Nọ́mbà Tíkòsí
  • Nọ́mbà Tósòro
  • Nọ́mbà Apáòsì
  • Nọ́mbà Apáọ̀tún
  • Nọ́mbà Àdábá
  • Nọ́mbà Odidi
  • Nọ́mbà Oníìpín
  • Nọ́mbà Aláìníìpín
  • Nọ́mbà Gidi
  • 'Awon Eka Imo Isiro'
    Eko Isiro Ipilese Imo Isiro Ero Nomba Imo Isiro Onijinle
    • Awon Onimo Isiro
    • Itan Imo Isiro
    • Imo Oye L'ori Isiro
    • Sise Ami Isiro
    • Ewa Imo Isiro
    • Eko Imo Isiro
    • Area of mathematics
    • Ipilese Imo Isiro
    • Ero Ikojopo
      • Naive set theory
      • Axiomatic set theory
    • Mathematical logic
    • Ero nipa Ise afihan
    • Ero Ise Afiwe
    • Category theory
      • Topos theory
    • Awon agbagbo aipeyekun Gödel
    • Imo Isiro Onijinle
    • Combinatorics
    • Ero Iwon Ila
    • Ero Ibanisere
    • Iwon Itobiile Onijinle
    • Ero Imo Sayensi Ero Olonka
      • Ero L'ori Onka
      • Complexity theory
    • Ero Ise Ikede
    Agbeyewo Ninu Imo Isiro Aljebra Alawonile ati Ibamuile Imo Isiro Oniwulo
    • Analysis
    • Isiro Kalkulosi
      • Isiro Kakulosi Igbegbooro
      • Idogba Iseyato
      • Isiro Kalkukosi Oniyekiye
    • Isiro Agbeyewo Gidi
    • Complex analysis
    • Agbeyewo Alabase
    • Agbeyewo Onibamu
    • Ero L'ori Iwon
    • Awon Alabase Otoo
    • Isiro Iseiwon Onigun
    • Ipilese Agbagbo Isiro Kalkulosi
    • Áljẹ́brà
    • Aljebra Akokose
    • Aljebra Afoyemo
      • Ero Group theory
      • Ero Oruka
      • Field theory
      • Aljebra adípò
    • Áljẹ́brà alátẹ̀lé
      • Ero Akopapo
    • Aljebra alatele olopolopo
    • Aljebra agbala-aye
    • Ero Eto (Order theory)
    • Ipilese agbagbo aljebra
    • Alawonile
    • Ibamuile - Topology
      • General topology
      • Algebraic topology
      • Geometric topology
    • Itobi Ile Efklidi
    • Itobi Ile ti kise ti Efklidi
    • Affine geometry
    • Projective geometry
    • Differential geometry
      • Riemannian geometry
      • Lie groups
    • Algebraic geometry
    • Four color theorem
    • Pythagorean theorem
    • Isiro Oniwulo
    • Agbeyewo Nomba
    • Mathematical biology
    • Optimization
    • Dynamical systems
      • Ero Idaru
    • Financial mathematics
    • Cryptography
    • Mathematical physics
      • Classical mechanics
    • Probability
    • Statistics
    • Operations research