Ìfẹ́ Orílẹ́-èdè Ẹni

Ìfẹ́ Orílẹ́-èdè Ẹni jẹ́ aáyan ìfọkànsìn láti fìfẹ́hàn fún orílẹ̀-èdè ẹni ní ìfọwọ́sọwọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn ará ìlú tí ìṣẹ̀dá wọn jọra. Èyí lè jẹ́ àpapọ̀ orísìírísìí àdámọ́ tó jẹ mọ́ ìlú ẹni; lára wọn ni ẹ̀yà, àṣà, ètò-òṣèlú tàbí ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀. Ó jẹ́ àkójọpò ìmọ̀ tó sunmo ìgbórílẹ̀-èdè ẹni ga  (nationalism).[1][2][3]

Allegory of Patriotism in the Monument to the Fallen for Spain in Madrid (1840), by sculptor Francisco Pérez del Valle

References