Adam Smith
Adam Smith (iribomi 16 June 1723 – alaisi 17 July 1790 [OS: 5 June 1723 – 17 July 1790]) je amoye alawujo ati asiwaju ninu eko itokowo oloselu ara Skotlandi. Enikan pataki ninu Olaju Skotlandi, Smith ni o ko iwe The Theory of Moral Sentiments ati An Inquiry into the Nature and Causes of the Wealth of Nations to gbajumo lasan bi The Wealth of Nations, je gbigba bi ise ninla re ati iwe akoko odeoni nipa isiseitokowo. O je ko gbajumo gidigidi be sini yio je ki o nikopa lori isiseitokowo titi doni. Smith je titokasi kakiri gege bi baba isiseitokowo ati iseowoele.
Adam Smith | |
---|---|
Orúkọ | Adam Smith |
Ìbí | 5 June 1723 Kirkcaldy, Scotland |
Aláìsí | 17 July 1790 Edinburgh, Scotland | (ọmọ ọdún 67)
Ìgbà | Classical economics (Modern economics) |
Agbègbè | Western philosophy |
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ | Classical economics |
Ìjẹlógún gangan | Political philosophy, ethics, economics |
Àròwá pàtàkì | Classical economics, modern free market, division of labour, the "invisible hand" |
Ìtọwọ́bọ̀wé |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Wikipedia:Nípa WikipediaOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWikipedia:Èbúté ÀwùjọÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíPàtàkì:SearchWikipediaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Èdè YorùbáÀṣà YorùbáÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgBobriskyWikipedia:Abẹ́ igiPraguePàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunLinda IkejiWikipedia:Àyọkà pàtàkìPàtàkì:ÀwọnÀfikúnMiMọ́remí ÁjàṣoroFáwẹ̀lì YorùbáPornhubOwe YorubaÀmìọ̀rọ̀ QREre idarayaISO 8601Ògún LákáayéOrúkọ YorùbáÈdè Gẹ̀ẹ́sìIṣẹ́ Àgbẹ̀OSI modelIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanẸ̀ka:Àwọn Àyọkà pẹ̀lú ìjúwe ṣókíÌgbéyàwóHTMLKikan Jesu mo igi agbelebuÀrokòISBN