Ata Tàtàṣé

Ata Tàtàṣé (Látìnì: capsicum annuum) ni wọ́n tún ń dà pe ní sweet pepper, bell pepper, paprika tàbí ní èdè Gẹ̀ẹ́sì /ˈkæpskəm/)[1][2] Ata yí ma ń ní ẹ̀yà ewébẹ̀ tí a fi ń ṣe ohun jíjẹ, tí ó ma ń ní oríṣiríṣi àwọ̀ bí :àwọ̀ pupa, funfun, àwọ̀ ewé, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ata tàtàṣé kìí sábà ta ní tirẹ̀, nítorí wípé ó ma ń dùn ní tirẹ̀.[3] agbègbè tí ata yí ti fẹ́ràn jùlọ láti màa dàgbà aí ni ibi tí ó bá lọ́ wọ́rọ́ bí ìwòn 21 to 29 °C (70 to 84 °F).[4]

àwòrán ata tàtàṣé

Àwọn Ìtọ́kasí