Brad Pitt

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Brad Pitt jẹ́ òṣèré eré orí ìtàgé àti atọ́kùn eré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó ti gba ẹ̀bùn akádẹ́mì lẹ́ẹ̀mẹ́ta gẹ́gẹ́ bí olùgbéjáde eré lábẹ́ ilé iṣẹ́rẹ̀, Plan B Entertainment.Pitt kọ̣́kọ́ di mímọ̀ gẹ́gẹ́ bíi darandaran nínú eré Thelma & Louise (1991).[1][2]

Brad Pitt
Pitt smiling
Brad Pitt - Hollywood California - July 2019
Ọjọ́ìbíWilliam Bradley Pitt
Oṣù Kejìlá 18, 1963 (1963-12-18) (ọmọ ọdún 60)
Shawnee, Oklahoma, U.S.
Iṣẹ́Actor, producer
Ìgbà iṣẹ́1987–present
Olólùfẹ́
Jennifer Aniston
(m. 2000; div. 2005)

Angelina Jolie (m. 2014)
Àwọn ọmọ6
Àwọn olùbátanÀdàkọ:Plain list

Àwọn eré tí ó ti kópa

  • Thelma & Louise (1991)
  • A River Runs Through It (1992)
  • Kalifornia (1993)
  • True Romance (1993)
  • Interview with the Vampire (1994)
  • Legends of the Fall (1994)
  • Seven (1994)
  • 12 Monkeys (1995)
  • Sleepers (1996)
  • Seven Years in Tibet (1997)
  • Meet Joe Black (1998)
  • Fight Club (1999)
  • Snatch (2000)
  • The Mexican (2001)
  • Spy Game (2001)
  • Ocean's Eleven (2001)
  • Troy (2004)
  • Ocean's Twelve (2004)
  • Mr. & Mrs. Smith (2005)
  • Babel (2006)
  • The Assassination of Jesse James by the Coward Robert Ford (2007)
  • Ocean's Thirteen (2007)
  • The Curious Case of Benjamin Button (2008)
  • Inglourious Basterds (2009)
  • Tree of Life (2011)
  • Moneyball (2011)
  • World War Z (2013)
  • 12 Years a Slave (2013)
  • Fury (2014)
  • The Big Short (2015)
  • Allied (2016)

Àwọn ìtọ́kasí