Christian Wulff

Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Germany.

Christian Wilhelm Walter Wulff (ojoibi 19 June 1959) je oloselu omo ile Jemani ti egbe oloselu Christian Democratic Union. O je Aare ile Jemani lati 30 June 2010 titi di 17 February 2012.[1]

Christian Wulff
Wulff in 2009.
President of Germany
In office
30 June 2010 – 17 February 2012
ChancellorAngela Merkel
AsíwájúHorst Köhler
Arọ́pòJoachim Gauck
Minister-President of Lower Saxony
In office
4 March 2003 – 30 June 2010
AsíwájúSigmar Gabriel
Arọ́pòDavid McAllister
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí19 Oṣù Kẹfà 1959 (1959-06-19) (ọmọ ọdún 64)
Osnabrück, Lower Saxony, Germany
Ẹgbẹ́ olóṣèlúChristian Democratic Union
Alma materUniversity of Osnabrück
ProfessionLawyer
Signature
WebsiteOfficial website



Itokasi