Donald Trump

Olóṣèlú

Donald John Trump (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹfà ọdún 1946) ni Ààrẹ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà ẹlẹ́ẹ̀karùndínláàdọ́ta lọ́wọ́lọ́wọ́ 45k, ó gorí àléfà ní Ogúnjọ́, oṣù kìíní ọdún 2017. Trump jẹ́ gbajúgbajà oníṣòwò kí ó tó dara pọ̀ mọ́ òṣèlú.

Donald Trump
45th President of the United States
In office
January 20, 2017 – January 20, 2021
Vice PresidentMike Pence
AsíwájúBarack Obama
Arọ́pòJoe Biden
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Donald John Trump

Oṣù Kẹfà 14, 1946 (1946-06-14) (ọmọ ọdún 77)
New York City
Ẹgbẹ́ olóṣèlúRepublican (1987–99, 2009–11, 2012–present)
Other political
affiliations
  • Democratic (until 1987, 2001–09)
  • Reform (1999–2001)
  • Independent (2011–12)
(Àwọn) olólùfẹ́
  • Ivana Zelníčková
    (m. 1977; div. 1992)
  • Marla Maples
    (m. 1993; div. 1999)
  • Melania Knauss (m. 2005)
Àwọn ọmọ
Àwọn òbí
  • Fred
  • Mary Anne
RelativesSee Family of Donald Trump
Residence
  • White House (official/primary)
  • Trump Natl. Bedminster (summer)
  • Mar-a-Lago (winter)
  • Trump Tower (private/secondary)
Alma materThe Wharton School (B.S. in Econ.)
Occupation
    • Real estate developer
    • (The Trump Organization)
    • Television host/producer
    • (The Apprentice)
Net worth US$3.5 billion (May 2017)
SignatureDonald J Trump stylized autograph, in ink
Website

[1] [2][3][4]

Àwọn Ìtọ́kasí