Káábà

Kaaba (Lárúbáwá: الكعبة‎ / DIN 31635: al-Kaʿbah / IPA: [ˈkɑʕbɐ] / English: The Cube)[1] ni ilé kékeré bí Apoti tí ó wà ní Mekka, Saudi Arabia, bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ ibi mímọ́ jùlọ nínú èsìn Imale.[2] Ilé yí ti wà ṣíwájú èsìn Ìmàle, gẹ́gẹ́ bí ìtàn ẹ̀sìn Islam ti fi lélẹ̀, ilé náà di kíkọ́ síbẹ̀ látọwọ́ òjísẹ́ Ọlọ́run Abraham. Ilé náà ni wọ́n kọ́ mosalasi yíká, Mosalasi Al Haram. Gbogbo àwọn musulumi kákiri ayé ló ma ń kọjú sí Kàábà tí wọ́n bá ń kirun ní yówù tí wọ́n bá wà lágbàáyé.

Kaaba
LocationSáúdí Arábíà Mecca, Saudi Arabia
Branch/traditionIslam




Itokasi

39°49′34″E / 21.42250°N 39.82611°E / 21.42250; 39.82611