Màríà (ìyá Jésù)

Màríà (èdè Aramaiki, èdè Heberu: מרים, Maryām Miriam; èdè Arabu:مريم, Maryam), ti awon omo leyin Kristi n pe ni Mariamo, Maria Wundia tabi Maria Mimo ati nigba miran Madonna, je obinrin Ju ara Nazareth ni Galilee, ti Majemu Tuntun[Mt. 1:16,18–25] [Lk. 1:26–56] [2:1–7] tokasi gege bi iya Jesu Kristi. Awon musulumi na un pe ni Maria Mimo tabi Syeda Mariam, to tumosi Màríà Ìyá Wa. Majemu Tuntun se apejuwe re bi wundia (Griiki παρθένος, parthénos).[3] Awon Elesin Kristi gbagbo pe o loyun Jesu nipa Emin Mimo.

Màríà, Ìyá Jésù
Mary, Mother of Jesus
The Madonna in Sorrow, by Sassoferrato, 17th century.
Theotokos ("Mother of God")
Blessed Virgin Mary
Umm Issa ("Mother of Jesus")
Saint Mary
Bornunknown; celebrated 8 September [1]
Diedunknown; See Assumption of Mary
Venerated inAnglican Communion
Eastern Orthodoxy
Lutheranism[2]
Oriental Orthodoxy
Catholic Church

Recognized and honored
(not venerated) in:

Islam

Protestantism
Major shrineSee Shrines to the Virgin Mary
FeastMary is commemorated on as many as 25 different days. The most universally observed are:

25 March – The Annunciation15 August – The Assumption (Catholicism)
15 August – The Dormition (Orthodoxy)

22 August – The Assumption Coptic-Orthodox
PatronageSee Patronage of the Blessed Virgin Mary




Itokasi