Ọ̀fun
Ọ̀fun ( /ᵻˈsɒfəɡəs/), tí a tún mọ̀ sí ònfà óúnjẹ ni ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà ara inú tí ó dàbí okùn oníhò tí ó ń ṣíṣẹ́ gbígbé óúnjẹ láti ẹnu lọ sí inú ikùn tí ó wà ní ara gbogbo ohun abẹ̀mi tí ó bá ti ń jẹ tàbí mu ohun kóhun. fibromuscular. Ọ̀fun yí dà bí ahòho tí ó gùn ní ìwọ̀n mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n lára àgbàlagba ènìyàn tí ó rọra gba ẹ̀yìn okùn ohùn, ọkàn àti iṣan atẹ́gùn tàbí èémí kọjá, tí ó sì fẹnu sọlẹ̀ sí inú ikùn. Lásìkò tí a bá ń gbé óúnjẹ mì lọ́wọ́, gògóńgò yóò dípa lọ́wọ́ ẹ̀yín kí a má ba lè gbé óúnjẹ párí. [1]
Esophagus | |
---|---|
The digestive tract, with the esophagus marked in red | |
Details | |
Precursor | Foregut |
System | Part of the digestive system |
Artery | Oesophageal arteries |
Vein | Oesophageal veins |
Nerve | Sympathetic trunk, vagus |
Identifiers | |
Latin | Oesophagus |
TA | A05.4.01.001 |
FMA | 7131 |
Anatomical terminology |
Àwọn Ìtọ́ka sí
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Wikipedia:Nípa WikipediaOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWikipedia:Èbúté ÀwùjọÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíPàtàkì:SearchWikipediaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Èdè YorùbáÀṣà YorùbáÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgBobriskyWikipedia:Abẹ́ igiPraguePàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunLinda IkejiWikipedia:Àyọkà pàtàkìPàtàkì:ÀwọnÀfikúnMiMọ́remí ÁjàṣoroFáwẹ̀lì YorùbáPornhubOwe YorubaÀmìọ̀rọ̀ QREre idarayaISO 8601Ògún LákáayéOrúkọ YorùbáÈdè Gẹ̀ẹ́sìIṣẹ́ Àgbẹ̀OSI modelIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanẸ̀ka:Àwọn Àyọkà pẹ̀lú ìjúwe ṣókíÌgbéyàwóHTMLKikan Jesu mo igi agbelebuÀrokòISBN