Annona squamosa


Annona squamosa jẹ́ igi kékeré tàbi igi kúkurú[1] láti ìdílé Annonaceae tó ń so èso tó ṣe é jẹ, tí wọ́n ń pè ní sugar apples tàbí sweetsops.[2] Ó máa ń gba ìwọ̀n ojú ọjọ́ tó lọlẹ̀ díẹ̀ bí i ti Annona reticulata àti Annona cherimola (tí èso rẹ̀ sì ń jẹ́ orúkọ kan náà) tó sì máa ń mu rọrùn fún àwọn ẹ̀ka yòókù láti hù.[3] Annona squamosa jẹ́igi kékeré,[4] tó ga tó ìwọ̀n 3 to 8 metres (10 to 26 feet) [1][4] èyí tó jọ ti soursop (Annona muricata).[5] Ó jẹ́ ìbílẹ̀ sí tropical climate ní America àti West Indies, àti àwọn tó ń ṣe ìdókòwò ní Spain sí Asia.[6]

Description

Flower
Seedling
Branches

Èṣo A. squamosa (sugar-apple) ní adùn aláwọ̀ funfun, ó sì gbajúmọ̀ ní àwọn ọjà ńlá.

Ẹ̀ka àti ewé

A. squamosa leaves

Ẹ̀ka rẹ̀ ní àwọ pálí pẹ̀lú egbò igi lára rẹ̀; twig rẹ̀ máa ń yí àwọ̀ padà pẹ̀lú àmì tó tò tò tó.

Ìwúlò

Sugar-apple ní energy, ó sì jẹ́ orísun vitamin C àti manganese, ó sì tún jẹ́ orísun thiamine àti vitamin B6, ó sì tún máa ń pèsẹ̀ vitamin B2, B3 B5, B9, iron, magnesium, phosphorus àti potassium ní ìwọ̀n tó tọ́.[7]

Michał Boym's drawing of, probably, the sugar-apple, in his Flora Sinensis (1655)

Àwọn ìtọ́kasí