Bíbélì Mímọ́

Bíbélì Mímọ́, tabi Bíbélì jẹ́ àkójọpọ̀ àwọn ìwé Ẹ̀sìn Ju àti Ẹ̀sìn Kristi.[1][2]

Bibeli Heberu tabi Bibeli Awon Ju da si apa meta:

  • Torah, tabi "Ilana" ti a mo si Pentatefki tabi "Iwe Marun Mósè"
  • Nefimu, tabi "Awon Woli"
  • Ketufimu, "Akole mimo"
Bíbélì Mimọ

Bibeli awon Ẹlẹ́sìn Kristi da si apa meji.

Apa Kinni

  1. Genesisi
  2. Eksodu
  3. Lefitiku
  4. Numeri
  5. Deuteronomi
  6. Josua
  7. Ìwé àwọn Onídàjọ́
  8. Rutu
  9. Samueli 1
  10. Samueli 2
  1. Àwọn Ọba 1
  2. Àwọn Ọba 2
  3. Kronika 1
  4. Kronika 2
  5. Esra
  6. Nehemiah
  7. Esteri
  8. Joobu
  9. Psalmu
  10. Òwe
  1. Oniwasu
  2. Orin Solomoni
  3. Isaiah
  4. Jeremiah
  5. Ẹkún Jeremiah
  6. Esekieli
  7. Danieli
  8. Hosea
  9. Joeli
  10. Amosi
  1. Obadiah
  2. Jona
  3. Mika
  4. Nahumu
  5. Habakkuku
  6. Sefaniah
  7. Haggai
  8. Sekariah
  9. Malaki

Apa Keji

  1. Ihinrere Matteu
  2. Ihinrere Marku
  3. Ihinrere Luku
  4. Ihinrere Johanu
  5. Ise Awon Aposteli
  6. Awon Ara Romu
  7. Awon Ara Korinti 1
  8. Awon Ara Korinti 2
  9. Awon Ara Galatia
  10. Awon Ara Efesu
  1. Awon Ara Filippi
  2. Awon Ara Kolosse
  3. Awon Ara Tessalonika 1
  4. Awon Ara Tessalonika 2
  5. Timoteu 1
  6. Timoteu 2
  7. Titu
  8. Filemoni
  9. Awon Heberu
  10. Jemisi
  1. Peteru 1
  2. Peteru 2
  3. Johanu 1
  4. Johanu 2
  5. Johanu 3
  6. Juda
  7. Ifihan


Itokasi