Dígí
Dígí tàbí Díngí ìwògbè ni ohun èlò kan tí a ń lò láti fi wo àwòrán ara ẹni tí yóò sì gbé àwòrán náà wá fúni gẹ́gẹ́ a ti rí.[1]
Oríṣi dígí tí ó wà
Lára àwọn dígí tí ó wọ́pọ̀ tí a má ń rí tàbí lò jùlọ ni panragandan (plain mirror). Èkejì ni dígí ẹlẹ́bùú (cirved mirror), wọ́n ma ń lo[2] dígí yìí láti fi pèsè irúfẹ́ àwọn dígí mìíràn tí a lè fi wo ohun tó bá wẹ́ níye.
Ìwúlò dígí
- A ma ńblo dígí fún oríṣríṣi nkan. Lára rẹ̀ ni kí á fi wo ara ẹni yálà ojú tàbí ibi kọ́lọ́fín tí ojú kò lè ká lára. Ìdí nìyí tí Yorùbá fi ma ń pèé ní ìwògbè.
- Wọ́n ms ń lo dígí fún wíwo ẹ̀yìn lára ọkọ̀, kẹẹ̀kẹ́ ológere, Kẹ̀kẹ́ Alùpùpù àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. [3]
- Wọ́n ma ń lòó láti fi ṣẹ̀ṣọ́ ara Ilé.
- Àwọn Dókítà olùtọ́jú eyín náà ma ń lòó láti fi wo kọ̀rọ̀ ẹnu
- Wọ́n ń lo dígí láti fi pèsè ìléjú ẹ̀rọ ayàwòrán àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Àwọn Ìtọ́ka sí
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Wikipedia:Nípa WikipediaOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWikipedia:Èbúté ÀwùjọÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíPàtàkì:SearchWikipediaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Èdè YorùbáÀṣà YorùbáÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgBobriskyWikipedia:Abẹ́ igiPraguePàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunLinda IkejiWikipedia:Àyọkà pàtàkìPàtàkì:ÀwọnÀfikúnMiMọ́remí ÁjàṣoroFáwẹ̀lì YorùbáPornhubOwe YorubaÀmìọ̀rọ̀ QREre idarayaISO 8601Ògún LákáayéOrúkọ YorùbáÈdè Gẹ̀ẹ́sìIṣẹ́ Àgbẹ̀OSI modelIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanẸ̀ka:Àwọn Àyọkà pẹ̀lú ìjúwe ṣókíÌgbéyàwóHTMLKikan Jesu mo igi agbelebuÀrokòISBN