Guinea

Guinea (pípè /ˈɡɪni/, lonibise bi Orile-ede Olominira ile Guinea Faransé: République de Guinée), je orile-ede kan ni Iwoorun Afrika. Mimo teletele bi Guinea Faranse (Guinée française), nigba miran loni bi Guinea-Conakry lati seyato re si Guinea-Bissau to wa legbe re.[5] Conakry ni oluilu, ibujoko ijoba olomoorile-ede ati ilu ttobijulo.

Republic of Guinea

Flag of Guinea, République de Guinée (French)
Àsìá
Motto: "Travail, Justice, Solidarité" (Faransé)
"Work, Justice, Solidarity"
Orin ìyìn: Liberté  (Faransé)
Freedom
Ibùdó ilẹ̀  Guinea  (dark blue) – ní Africa  (light blue & dark grey) – in the African Union  (light blue)
Ibùdó ilẹ̀  Guinea  (dark blue)

– ní Africa  (light blue & dark grey)
– in the African Union  (light blue)

Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Conakry
9°31′N 13°42′W / 9.517°N 13.700°W / 9.517; -13.700
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaFrench
Vernacular
languages
  • Fulani
  • Mandinka
  • Susu
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
(2014[1])
  • 34.6% Fula
  • 24.9% Mandinka
  • 17.7% Susu
  • 4.5% Koniaka
  • 4.1% Kissi
  • 4.0% Kpelle
  • 10.2% others
Orúkọ aráàlúGuinean
ÌjọbaUnitary presidential republic
• President
Mamadi Doubouya
Bah Oury
AṣòfinNational Assembly
Independence
• from France
2 October 1958
Ìtóbi
• Total
245,857 km2 (94,926 sq mi) (77th)
• Omi (%)
negligible
Alábùgbé
• Àdàkọ:UN Population estimate
Àdàkọ:UN PopulationÀdàkọ:UN Population (77th)
• 2014 census
11,523,261[1]
• Ìdìmọ́ra
40.9/km2 (105.9/sq mi) (164th)
GDP (PPP)2020 estimate
• Total
$26.451 billion[2]
• Per capita
$2,390[2]
GDP (nominal)2020 estimate
• Total
$9.183 billion[2]
• Per capita
$818[2]
Gini (2012)33.7[3]
medium
HDI (2018) 0.466[4]
low · 174th
OwónínáGuinean franc (GNF)
Ibi àkókòUTCÀdàkọ:Sp (GMT)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù+224
ISO 3166 codeGN
Internet TLD.gn



Itokasi