Guinea-Bissau

Guinea-Bissau tabi Orile-ede Olominira ile Guinea-Bissau (pípè /ˈɡɪni bɪˈsaʊ/; Pọrtugí: República da Guiné-Bissau, pípè [ʁɛˈpublikɐ dɐ ɡiˈnɛ biˈsaw]) budo si Iwoorun Afrika. O ni bode mo Senegal ni ariwa, ati Guinea ni guusu ati ilaorun, ati mo Okun Atlantiki ni iwoorun.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Guinea-Bissau
Republic of Guinea-Bissau

República da Guiné-Bissau
Motto: Pọrtugí: "Unidade, Luta, Progresso"  
"Unity, Struggle, Progress"
Orin ìyìn: Pọrtugí: "Esta é a Nossa Pátria Bem Amada"  
"This is Our Well-Beloved Motherland"
Location of Guinea-Bissau
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Bissau
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaPortugi
Lílò regional languagesCrioulo
Orúkọ aráàlúBissau-Guinean(s)[1]
ÌjọbaOrile-ede olominira sistemu aare die
• Aare
Umaro Sissoco Embaló
• Alakoso Agba
Rui Duarte de Barros
Ilominira 
latodo Portugal
• Fifilole
24 Osu Kesan, 1973
• Didamo
10 Osu Kesan, 1974
• Ojo Ajodun Orile-ede
24 Osu Kesan 24
Ìtóbi
• Total
36,125 km2 (13,948 sq mi) (136th)
• Omi (%)
22.4
Alábùgbé
• 2010 estimate
1,647,000[2] (148th)
• 2002 census
1,345,479
• Ìdìmọ́ra
44.1/km2 (114.2/sq mi) (154th)
GDP (PPP)2009 estimate
• Total
$1.720 billion[3]
• Per capita
$1,068[3]
GDP (nominal)2009 estimate
• Total
$826 million[3]
• Per capita
$512[3]
Gini (1993)47
high
HDI (2007) 0.396
Error: Invalid HDI value · 173rd
OwónínáWest African CFA franc (XOF)
Ibi àkókòUTC+0 (GMT)
Ojúọ̀nà ọkọ́otun
Àmì tẹlifóònù245
Internet TLD.gw

Aala ile re to 37,000 square kilometres (14,000 sq mi) pelu awon olugbe ti idiye won to 1,600,000.

Guinea-Bissau je ara ileoba Gabu nigbakan, to je apa Ileobaluaye Mali; awon apa ileoba wa titi di orundun kejidinlogun, nigba ti awon miran si je apa Ileobaluaye Portugal. Nigba na lo wa di ibiamusin Portugal toruko re unje Guinea Portugi ni orundun 19th. Leyin ilominira, to je fifilole ni 1973 to si je didamo ni 1974, oruko oluilu re, Bissau, je fifikun mo oruko orile-ede lati dena iaru po mo Orile-ede Olominira ile Guinea.

14% nikan awon olugbe ni won mo ede onibise, Portugi so. Awon 44% uso Kriol, ede to da lori Portugi, awon yioku unso awon ede abinibi Afrika. Awon esin kanka ibe ni esin Islam ati awon esin ibile Afrika.

O je omo egbe Isokan Afrika, Agbajo Okowo awon Orile-ede Iwoorun Afrika, Agbajo Ipejo Onimale, Isokan Latini, Agbajo awon Orile-ede Ede Portugi, La Francophonie ati South Atlantic Peace and Cooperation Zone.

Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè tenikookan re je ikan larin awon tokerejulo lagbaye.

Itan

Ilominira

Iselu

Awon agbegbe ati apa ile Guinea-Bissau

Guinea-Bissau je pipin si awon agbegbe 8 ([regiões] error: {{lang}}: text has italic markup (help)) ati apa ibi aladawa kan ([sector autónomo] error: {{lang}}: text has italic markup (help)). Awon wonyi na tun wa je pinpin si apa metadinlogoji. Awon agbegbe ohun niyi:

  • Bafatá
  • Biombo
  • Bissau*
  • Bolama
  • Cacheu
  • Gabu
  • Oio
  • Quinara
  • Tombali
* autonomous sector
Map of the regions of Guinea-Bissau

Jeografi

Awon ilu pataki

Cities in Guinea-Bissau
RankCityPopulationRegion
1979 Census2005 estimate
1Bissau109,214388,028Bissau
2Bafatá13,42922,521Bafatá
3Gabú7,80314,430Gabú
4BissorãN/A12,688Oio
5Bolama9,10010,769Bolama
6Cacheu7,60010,490Cacheu
7Bubaque8,4009,941Bolama
8Catió5,1709,898Tombali
9Mansôa5,3907,821Oio
10BubaN/A7,779Quinara
11QueboN/A7,072Quinara
12Canchungo4,9656,853Cacheu
13Farim4,4686,792Oio
14QuinhámelN/A3,128Biombo
15FulacundaN/A1,327Quinara

Ojuojo

Okowo

Aworan

Demografiki

Líla odò ni kekere ṣiṣan
Religion in Guinea-Bissau,[4][5]
religionpercent
Islam
  
50%
Indigenous
  
40%
Christianity
  
10%

Awon eya eniyan

Ede

Esin

Ilera

Eko

Asa


Orisun

  • Joshua B. Forrest, Lineages of State Fragility. Rural Civil Society in Guinea-Bissau (Ohio University Press/James Currey Ltd., 2003).
  • Richard Andrew Lobban, Jr. and Peter Karibe Mendy, Historical Dictionary of the Republic of Guinea-Bissau, third edition (Scarecrow Press, 1997) ISBN 0-8108-3226-7 (includes extensive bibliography)

Ijapo lode

Àdàkọ:Sisterlinks

Government
Awifun gbogbogbo
Iroyin

Itokasi