Martin Luther King, Jr.

Olóṣèlú

Martin Luther King, Jr.(January 15, 1929 – April 4, 1968) jẹ́ ẹni ọ̀wọ̀, alákitiyan ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà,[1]bẹ́ẹ̀ ni ó sí jẹ́ olórí ẹgbẹ́-ìjíndé fún ẹ̀tọ́ ọmọ-àwùjọ ni ilé Amẹ́ríkà. Gẹ́gẹ́ bí oníwasú Ìjọ Onítẹ̀bọmi, King di alakitiyan fún ẹ́tọ́ ará-ìlú ní ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀.

Dr. Martin Luther King, Jr.

Ọjọ́ ìbí:(1929-01-15)Oṣù Kínní 15, 1929
Place of birth:Atlanta, Georgia, USA
Ọjọ́ aláìsí:April 4, 1968(1968-04-04) (ọmọ ọdún 39)
Place of death:Memphis, Tennessee, USA
Movement:African-American Civil Rights Movement and Peace Movement
Major organizations:Southern Christian Leadership Conference
Notable prizes:Nobel Peace Prize (1964)
Presidential Medal of Freedom (1977, posthumous)
Congressional Gold Medal (2004, posthumous)
Major monuments:Martin Luther King, Jr. National Memorial (planned)
Religion:Baptist
InfluencesHoward Thurman, Mahatma Gandhi, Henry David Thoreau, Bayard Rustin, Jesus Christ
InfluencedCoretta Scott King, Jesse Jackson

Ìgbà èwe rẹ̀

Àwọn Ìtọ́ka sí