Oprah Winfrey
Oprah Gail Winfrey ( /ˈoʊprə/; orúkọ àbísọ rẹ̀ ni Orpah Gail Winfrey;[2] a bi ní ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù kínní ọdun 1954) jẹ́ asọ̀rọ̀ lórí ẹ̀rọ ìmóhùnmáwòrán, òsèrẹ́binrin àti Olùkọ̀wé ọmọ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Àwọn ènìyàn mọ́ fún àwọn ọ̀rọ̀ rẹ̀ lórí The Oprah Winfrey Show, èyí tí wọ́n ma ń gbé sí afẹ́fẹ́ láti Chicago, ìwọ̀rọ̀ wé ọ̀rọ̀ orí ìmóhùnmáwọ́ràn fún ọdun meedọ́gbọ̀n, láti ọdun 1986 sí ọdun 2011.[3][4] Àwọn ènìyàn fún Oprah ní orúkọ "Queen of All Media",[5] Òun ni ará Africa mó Amerika tí olówó julọ ni ayé òde òní.[6][7] Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ni wọ́n ti pé ní obìnrin tí ó níyì julọ ní àgbáyé.[8][9]
Oprah Winfrey | |
---|---|
Winfrey ni ọdun 2014 | |
Ọjọ́ìbí | Orpah Gail Winfrey Oṣù Kínní 29, 1954 Kosciusko, Mississippi, U.S. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Tennessee State University (BA) |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1973–present |
Works | Media projects |
Title | Àdàkọ:Indented plainlist |
Political party | Independent |
Alábàálòpọ̀ | Stedman Graham (1986–present) |
Àwọn ọmọ | 1[lower-alpha 1][1] |
Awards | Full list |
Website | oprah.com |
Signature | |
Ìtàn ìgbésí ayé rẹ̀
Wọ́n bí Orpah Gail Winfrey ní ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù kínní ọdun 1954; orúkọ rẹ̀ àkọ́kọ́ ni Orpah àwọn òbí rẹ̀ fun ní orúkọ yìí tẹ̀lẹ́ ẹnìkan nínú ìwé Rutu ti inú ìwé mímọ́, orúkọ yìí sì ni ó wà lórí ìwé ẹrí ìbí rẹ̀, ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn ma ń ṣì orúkọ rẹ̀ pè, tí wón sì ma ń pè ní "Oprah".[2][10] Ìyá tí ó bí jẹ́ omidan tí kò tí gbéyàwó, ó bi ní Kosciusko, Mississippi.[11]
Àwọn Ìtọ́kasí
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/>
tag was found