Okoẹrú
Okoẹrú jẹ́ ìṣe ayé àtijọ́ tí àwọn ènìyàn kan máa ń ṣe káràkátà ọmọ ènìyàn mìíràn fún àwọn alágbára tàbí àwọn òyìnbó amúnisìn. Nínú okowò ẹrú, ọmọ ènìyàn ni ọjà tí wọ́n ń tà. Wọ́n máa ń kó àwọn ènìyàn tí wọ́n tà lẹ́rú lọ ṣiṣẹ́ oko àti àwọn ìṣe líle ni ìlú òyìnbó. Àwọn tí wọ́n bá kò lẹ́rú kì í ní òmìnira kankan bẹ́ẹ̀ sì ni wọ́n fi wọ́n ṣiṣé ní tipátipá.[1][2][3]
Àwọn ìtọ́kasí
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Ọ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Pàtàkì:SearchEre idarayaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáIṣẹ́ Àgbẹ̀Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìÀṣà YorùbáÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáÒgún LákáayéWikipedia:Nípa WikipediaWikipediaOwe YorubaAkanlo-edeỌrọ orúkọOrúkọ YorùbáWikipedia:Èbúté ÀwùjọHóséà Ayoola AgboolaÈdè YorùbáPàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunWikipedia:Abẹ́ igiÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Wikipedia:Àwọn àyọkà kúkúrúFáwẹ̀lì YorùbáÒrò àyálò YorùbáGbólóhùn YorùbáÀwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáAṣọHerbert MacaulayMọ́remí ÁjàṣoroṢàngóOmiEwìItan Ijapa ati AjaÀrokòAustrálíàIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Yewa