Àwọn Króátì

Àwọn Króátì (Kroatíà: [Hrvati] error: {{lang}}: text has italic markup (help)) ni awon eya eniyan Guusu Slafiki ti won unsaba gbe ni Kroatia, Bosnia ati Herzegovina ati awon awon orile-ede to sunmo won. Awon Kroati bi egbegberun 4 ni won ungbe ni Kroatia, ati idiye bi egbegberun 4.5 kakiri ibi to ku lagbaye.[1][23]

Croats
Hrvati
Àwọn Króátì
Demetrius Zvonimir · Klović · Vrančić · Gundulić · Zrinski
Frankopan · Bošković · Jelačić · Bukovac · Mohorovičić
Vučetić · Penkala · Meštrović · Ujević · Andrić
Prelog · Malkovich · Novoselic · Šuker ·Soljačić
Balić · Kostelić · Vlašić · Ančić · Čilić
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
7-9 million (est)[1]
Regions with significant populations
 Croatia 3,977,171[2]
 Bósníà àti Hẹrjẹgòfínà659,718 (2009)[3]
 Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan420,763 (2007)[4]
 Tsílè380,000[5]
 Argẹntínà250,000[5]
 Jẹ́mánì227,510[5]
 Austríà150,719[6]
 Austrálíà118,046 (2006)[7]
 Kánádà110,880[8]
 Sérbíà70,602[9]
 Brasil45,000 (est)[5]
 Swítsàlandì40,484(2006)[10]
 Sloféníà35,642 (2002)[11]
 Fránsì30,000(est)[12]
 Húngárì25,730[13]
 Itálíà21,360[14]
 Gúúsù Áfríkà8,000[15]
 Montenegro6,811 (2000)[16]
 Románíà6,786[17]
 Swídìn6,063[18]
 Dẹ́nmárkì5,400[19]
 Nọ́rwèy3,909[20]
 Slofákíà890[21]
 Bẹ́ljíọ̀m810[22]
Èdè

Croatian

Ẹ̀sìn

Predominantly Roman Catholic

Ẹ̀yà abínibí bíbátan

Other Slavic nations, especially South Slavs




Itokasi