Ìṣekọ́múnístì

Ìṣekọ́múnístì (Communism) je idimule awujo kan nibiti awon ipele eniyan kosi ati ti awon ohun ini wa labe idari gbogbo eniyan, o tun je imo oye oloselu ati irinkankan awujo to un sakitiyan ati to fe seda iru awujo bayi.[1]

Karl Marx so pe isekomunisti ni yio je itage ti yio dopin ninu awujo, ti yio sele latowo ijidide proletari ati leyin igba ti itage ti yio fa agbara apese, ti yio mu opo awon oja ati ipese wa.[2][3]


Itokasi