Ìkólẹ̀jọ Saint Martin

Saint Martin (Faransé: Saint-Martin), lonibise bi Ikolejo ile Saint Martin (French: Collectivité de Saint-Martin) je ikolejo okere ti France to budo si Kàríbẹ́ánì. O wa saye ni 15 July 2007[3], o si ni awon apaariwa erekusu Saint Martin ati awon erekusu kekere itosi re, ninu won ti eyi totobiju je Île Tintamarre.

Collectivity of Saint Martin

Collectivité de Saint-Martin
Flag of the Collectivity of Saint Martin
Àsìá
Àmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ the Collectivity of Saint Martin
Àmì ọ̀pá àṣẹ
Orin ìyìn: La Marseillaise
Location of the Collectivity of Saint Martin
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Marigot
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaFrench
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
Mulatto, West African, Mestizo (French-East Asia), European, East Indian[1]
Ìjọba
• President of France
Nicolas Sarkozy
• Prefect
Dominique Lacroix
• President of the Territorial Council
Frantz Gumbs
Overseas collectivity 
of France
• Island divided between France and the Netherlands
23 March 1648
• as separate Collectivity
15 July 2007
Ìtóbi
• Total
53.2 km2 (20.5 sq mi) (not ranked)
• Omi (%)
negligible
Alábùgbé
• Jan. 1, 2007 census
35,925[2]
• Ìdìmọ́ra
675/km2 (1,748.2/sq mi) (not ranked)
HDI (2003)n/a
Error: Invalid HDI value · n/a
OwónínáEuro (€) (EUR)
Ibi àkókòUTC-4
Àmì tẹlifóònù590
ISO 3166 codeMF
Internet TLD.mf assigned but not in use, .fr and .gp in use


Itokasi