Ìtàn

Ìtàn ni ìgbékalẹ̀ tàbí sísọ nípa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ohun tí ó ti kọjá. Yòóbá bọ̀, wọ́n ní "bọ́mọdé kò bá gbọ́tàn, a gbọ́ àrọ́bá...." Ìtàn lè wà ní àkọsílẹ̀ tàbí kí ó máà ní àkọsílẹ̀. Ìtàn máa ń jẹ́ kí a mọ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ méèlegbàgbé tí ó ṣẹlẹ̀ nígbà tí ènìyàn kò sí láyé tàbí wà níbi ìṣẹ̀lẹ̀ náà. [1] [2]

Ojuewe akole fun The Historians' History of the World.

Àwọn Ìtọ́kasí