Ẹgbẹ́ Rẹ̀públíkánì (USA)
Ẹgbẹ́-òṣèlú Rẹ̀púbílíkánnì (Republican Party) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú meji pàtàkì lónìí ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.Àwọn alátakò okowò ẹrú ló dá ẹgbẹ́ òṣèlú yìí sílẹ̀ lọ́dún 1854. Wọ́n pè é ní GOP tó dúró fún Grand Old Party, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹgbẹ́ òṣèlú yìí kéré sí ẹgbẹ́ rẹ̀ kejì lọ́jọ́ orí, àwọn ènìyàn gbà á gẹ́gẹ́ bí ẹgbẹ́ òṣèlú pàtàkì lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà
Republican Party | |
---|---|
Fáìlì:GOP Logo1.svg | |
Chairperson | Reince Priebus (WI) |
Senate Leader | Mitch McConnell (KY) |
House Leader | John Boehner (Speaker) (OH) Eric Cantor (Majority Leader) (VA) |
Chair of Governors Association | Rick Perry (TX) |
Ìdásílẹ̀ | 1854 |
Aṣíwájú | Whig Party Free Soil Party |
Ibùjúkòó | 310 First Street NE Washington, D.C. 20003 |
Ẹ̀ka akẹ́kọ̀ọ́ | College Republicans |
Ẹ̀ka ọ̀dọ́ | Young Republicans Teenage Republicans |
Ọ̀rọ̀àbá | Modern: • American conservatism • Social conservatism • Fiscal conservatism • Economic liberalism • Libertarian conservatism Historical: • Conservatives • Moderate Republicans • Libertarian Republicans Historical factions: • Radical Republicans • Carpetbagger • Scalawags • Stalwarts • Half-Breeds • Rockefeller Republicans |
Ìbáṣepọ̀ akáríayé | International Democrat Union |
Unofficial colors | Red |
Political position | Center-right |
Seats in the Senate | 47 / 100 |
Seats in the House | 240 / 435 |
Governorships | 29 / 50 |
State Upper Houses | 1,001 / 1,921 |
State Lower Houses | 3,021 / 5,410 |
Ibiìtakùn | |
http://www.gop.com/ |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Wikipedia:Nípa WikipediaOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWikipedia:Èbúté ÀwùjọÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyíPàtàkì:SearchWikipediaÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Èdè YorùbáÀṣà YorùbáÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàFáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgBobriskyWikipedia:Abẹ́ igiPraguePàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunLinda IkejiWikipedia:Àyọkà pàtàkìPàtàkì:ÀwọnÀfikúnMiMọ́remí ÁjàṣoroFáwẹ̀lì YorùbáPornhubOwe YorubaÀmìọ̀rọ̀ QREre idarayaISO 8601Ògún LákáayéOrúkọ YorùbáÈdè Gẹ̀ẹ́sìIṣẹ́ Àgbẹ̀OSI modelIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanẸ̀ka:Àwọn Àyọkà pẹ̀lú ìjúwe ṣókíÌgbéyàwóHTMLKikan Jesu mo igi agbelebuÀrokòISBN