Billie Eilish

Billie Eilish Pirate Baird O'Connell ( /ˈlɪʃ/ EYE-lish;[2] tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù Kejìlá ọdún 2001) jẹ́ akọrin ọmọ orílè-èdè Amerika. Ó di gbajúgbajà ní ọdún 2015 nígbà tí ó ṣe àgbéjáde orin "Ocean Eyes", tí arákùnrin rẹ̀ Finneas O'Connell kọ sílẹ̀. Ní ọdún 2017, ó sàgbéjáde orin extended play (EP), Don't Smile at Me.

Billie Eilish
Eilish ní ọdún 2023
Ọjọ́ìbíBillie Eilish Pirate Baird O'Connell
Oṣù Kejìlá 18, 2001 (2001-12-18) (ọmọ ọdún 22)
Los Angeles, California, U.S.
Iṣẹ́
  • Singer
  • songwriter
  • actress
Ìgbà iṣẹ́2015–present
Works
  • Discography
  • songs recorded
Parent(s)
  • Maggie Baird (mother)
Àwọn olùbátanFinneas O'Connell (brother)
Brian Baird (uncle)
AwardsFull list
Musical career
Irú orin
  • Pop
  • alt-pop
  • electropop
  • pop rock[1]
Instruments
  • Vocals
  • guitar
  • piano
  • ukulele
Labels
  • Darkroom
  • Interscope
Websitebillieeilish.com
Signature

Àwọn Ìtọ́kasí