Dàmáskù
Damascus (Lárúbáwá: دِمَشق Dimashq), ni Siria won unpe ni Al Sham (Lárúbáwá: الشام Al Shām), ati bi Ilu Jasmine (Lárúbáwá: مدينة الياسمين Madīnatu 'i Yāsmīn), ni oluilu ati ilu keji totobijulo ni Síríà ati ikan ninu awon igberiko 14 ni orile-ede na. Igberiko Damasku ni gomina bi olori toje yiyansipo latowo Alakoso Oro Abele. Damasku je gbangan asa ati esin pataki ni Lẹ̀fántì. Ilu na ni idiye olugbe 1,711,000 (idiye 2009).[1]
Damascus دِمَشق Dimashq | ||
---|---|---|
[[File:Damsacus infobox2.jpg|280px|Damascus City landmarks Damascus Skyline Damascus City landmarks Damascus Skyline | ||
| ||
Nickname(s): (Madīnatu 'l-Yāsmīn) City of Jasmin | ||
Country | Syria | |
Governorates | Damascus Governorate, Capital City | |
Government | ||
• Governor | Bishr Al Sabban | |
Area | ||
• City | 105 km2 (41 sq mi) | |
• Urban | 77 km2 (30 sq mi) | |
Elevation | 680 m (2,230 ft) | |
Population (2009 est.[1]) | ||
• City | 1,711,000 | |
Time zone | UTC+2 (EET) | |
• Summer (DST) | UTC+3 (EEST) | |
Area code(s) | Country code: 963, City code: 11 | |
Demonym | Damascene | |
Website | Damascus Governorate | |
Sources: Damascus city area [2] |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |