Pakístàn

orílẹ̀-èdè ní Ásíà

Pakístàn (/ˈpækɪˌstæn/  ( listen) tabi /ˌpɑkɨˈstɑːn/  ( listen); Urdu: پاکِستان) (Pípè ní Urdu: [paːkɪsˈtaːn]  ( ẹ tẹ́tí gbọ́)), lonibise bi Órílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Pakístàn (Urdu: اسلامی جمہوریہ پاکِستان) je orile-ede kan ni Guusu Asia. O ni ile etiomi to to 1,046-kilometre (650 mi) leba Omiokun Arabia ati Omiala Oman ni guusu, be sini o ni bode mo Afghanistan ati Iran ni iwoorun, India ni ilaorun ati Shaina ni ookan ni ariwailaorun.[7] Bakanna Tajikistan na sunmo Pakistan sugbon aaye Odede Wakhan tinrin pin won soto. Letanletan o budo si ipo larin awon agbegbe pataki Guusu Asia, Alaarin Asia ati Ibiarin Ilaorun.[8]

Órílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Pakístàn
Islamic Republic of Pakistan

اسلامی جمہوریہ پاکستان

Islāmī Jumhūrī-ye Pākistān

Motto: Unity, Discipline, Faith
(Urdu: اتحاد، تنظيم، يقين مُحکم)
Ittehad, Tanzeem, Yaqeen-e-Muhkam
Orin ìyìn: Qaumī Tarāna
Location of Pakistan
OlùìlúIslamabad
Ìlú tótóbijùlọKarachi
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaUrdu (National)
English
Lílò regional languagesBalochi, Pashto, Punjabi, Saraiki, Sindhi [1]
Orúkọ aráàlúPakistani
ÌjọbaFederal Parliamentary republic
• Founder
Muhammad Ali Jinnah
• President
Asif Ali Zardari (PPP)
• Prime Minister
Shehbaz Sharif (PML-N)
• Chief Justice
Qazi Faez Isa
• Chair of Senate
Sadiq Sanjrani (BAP)
• House Speaker
Raja Pervaiz Ashraf (PPP)
AṣòfinMajlis-e-Shoora
• Ilé Aṣòfin Àgbà
Senate
• Ilé Aṣòfin Kéreré
National Assembly
Formation
• Pakistan Declaration
January 1933
• Pakistan Resolution
23 March 1940
• Independence
from the United Kingdom
• Declared
14 August 1947
• Islamic Republic
23 March 1956
Ìtóbi
• Total
796,095 km2 (307,374 sq mi) (36th)
• Omi (%)
3.1
Alábùgbé
• 2024 estimate
170.6 million[2] (6th)
• 1998 census
132,352,279[3]
• Ìdìmọ́ra
214.3/km2 (555.0/sq mi) (55th)
GDP (PPP)2010 estimate
• Total
$451.972 billion[4]
• Per capita
$2,713[4]
GDP (nominal)2010 estimate
• Total
$177.901 billion[4]
• Per capita
$1,067[4]
Gini (2005)31.2
medium
HDI (2007) 0.572[5]
Error: Invalid HDI value · 141st
OwónínáPakistani Rupee (Rs.) (PKR)
Ibi àkókòUTC+5 (PST)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+6 (PDT)
Ojúọ̀nà ọkọ́left[6]
Àmì tẹlifóònù92
ISO 3166 codePK
Internet TLD.pk



Itokasi