Ọ́ksíjìn

Ọ́ksíjìn (play /ˈɒksɪɪn/ OK-si-jin) je elimenti kemika to ni nomba atomu 8 ati ti ami-idamo re je O. Oruko re wa lati gbongbo oro ede Griiki ὀξύς (oksis) (ikan, to je "shamu shamu", tountoka si ikan lenu awon ikan) ati -γενής (-jenis) (olupese, olumuwa), nitoripe nigba isoloruko re won ro pe gbogbo ikan gbodo ni oksijin ninu.

Ọ́ksíjìn, 8O
Ọ́ksíjìn
Ìhànsójúcolorless gas; pale blue liquid. Oxygen bubbles rise in this photo of liquid oxygen.
Ìwúwo átọ̀mù Ar, std(O)[15.9990315.99977] conventional: 15.999
Ọ́ksíjìn ní orí tábìlì àyè
HydrogenHelium
LithiumBerylliumBoronCarbonNitrogenOxygenFluorineNeon
SodiumMagnesiumAluminiumSiliconPhosphorusSulfurChlorineArgon
PotassiumCalciumScandiumTitaniumVanadiumChromiumManganeseIronCobaltNickelCopperZincGalliumGermaniumArsenicSeleniumBromineKrypton
RubidiumStrontiumYttriumZirconiumNiobiumMolybdenumTechnetiumRutheniumRhodiumPalladiumSilverCadmiumIndiumTinAntimonyTelluriumIodineXenon
CaesiumBariumLanthanumCeriumPraseodymiumNeodymiumPromethiumSamariumEuropiumGadoliniumTerbiumDysprosiumHolmiumErbiumThuliumYtterbiumLutetiumHafniumTantalumTungstenRheniumOsmiumIridiumPlatinumGoldMercury (element)ThalliumLeadBismuthPoloniumAstatineRadon
FranciumRadiumActiniumThoriumProtactiniumUraniumNeptuniumPlutoniumAmericiumCuriumBerkeliumCaliforniumEinsteiniumFermiumMendeleviumNobeliumLawrenciumRutherfordiumDubniumSeaborgiumBohriumHassiumMeitneriumDarmstadtiumRoentgeniumCoperniciumNihoniumFleroviumMoscoviumLivermoriumTennessineOganesson
-

O

S
nítrójìnọ́ksíjìnfluorínì
Nọ́mbà átọ̀mù (Z)8
Ẹgbẹ́group 16 (chalcogens)
Àyèàyè 2
Àdìpọ̀Àdìpọ̀-p
Ẹ̀ka ẹ́límẹ́ntì  Reactive nonmetal
Ìtò ẹ̀lẹ́ktrọ́nù[He] 2s2 2p4
Iye ẹ̀lẹ́ktrọ́nù lórí ìpele kọ̀ọ̀kan2, 6
Àwọn ohun ìní ara
Ìfarahàn at STPgas
Ìgbà ìyọ́54.36 K ​(-218.79 °C, ​-361.82 °F)
Ígbà ìhó90.20 K ​(-182.95 °C, ​-297.31 °F)
Kíki (at STP)1.429 g/L
when liquid (at b.p.)1.141 g/cm3
Critical point154.59 K, 5.043 MPa
Heat of fusion(O2) 0.444 kJ/mol
Heat of (O2) 6.82 kJ/mol
Molar heat capacity(O2)
29.378 J/(mol·K)
 pressure
P (Pa)1101001 k10 k100 k
at T (K)   617390
Atomic properties
Oxidation states−2, −1, 0, +1, +2
ElectronegativityPauling scale: 3.44
energies
  • (more)
Covalent radius66±2 pm
Van der Waals radius152 pm
Color lines in a spectral range
Color lines in a spectral range
Spectral lines of ọ́ksíjìn
Other properties
Natural occurrenceprimordial
Crystal structure ​cubic
Cubic crystal structure for ọ́ksíjìn
Speed of sound(gas, 27 °C) 330 m/s
Thermal conductivity26.58x10-3  W/(m·K)
Magnetic orderingparamagnetic
CAS Number7782-44-7
History
DiscoveryCarl Wilhelm Scheele (1772)
Named byAntoine Lavoisier (1777)
Main isotopes of ọ́ksíjìn
Iso­topeAbun­danceHalf-life (t1/2)Decay modePro­duct
16O99.76%16O is stable with 8 neutrons
17O0.039%17O is stable with 9 neutrons
18O0.201%18O is stable with 10 neutrons
Àdàkọ:Category-inline
| references

Ni igbonasi ati itemo opagun, atomu meji apilese na undipo lati da oksijinmeji kan (dioxygen), efuufu oniatomumeji alailawo, alailoorun, alainitowo to ni afida O2.

Oksijin je ikan ninu adipo kalkojin lori tabili alakoko, be sini o je apilese alaiseonide highly adarapo gidigidi to unda that readily forms adapo kiakia (agaga awon oloksijin) pelu gbogbo awon apilese yioku. Gegebi isupo re, oksijin ni apilese jantirerejulo keta ni agbalaye leyin haidrojin ati heliom[1] ati apilese tojantirere julo gegebi isupo ninu Earth's crust, o je bi idaji isupo crust.[2] Oksijin adawa je adarapo ni kemika julo lati han ni Aye laisi igbese afimoledapo awon iseelemin alaaye, ti won unlo okun imole orun lati se oksijin alapilese lati inu omi. O2 alapilese sese bere si pejo ninu afefeojuorun leyin ihanjade iyiarada awon iseelemin wonyi, ni bi odun 2.5 billion seyin.[3] Efuufu oksijin oniatomumeji lo je 20.8% itobiaye afefe.[4]

Nitori pe ohun ni opo isupo omi, oksijin na tun ni opo isupo awon iseelemin alaaye (fun apere, bi meji ninu idameta isupo ara omo eniyan). Gbogbo akosoto ninla awon igbonwo onilepo ninu awon iseelemin alaaye, bi proteins, karboniolomi, ati ora, ni oksijin ninu, bo se je bakanna fun awon adapo alailemin ninla ti won je ike, eyin ati egun awon eranko. Oksijin alapilese unje sise latowo cyanobacteria, algae ati awon ogbin, o si unje lilo ninu imin alahamo fun gbogbo emin tosoro. Oksijin se ipalara si awon iseelemin alailoafefe dandanundandan, ti won je iruida emin atetekose to gbale ni Aye ko to o dipe O2 bere sini pejo ninu afefeojuorun. Iruida miran (allotrope) oksijin, osoni (O3), seranlowo lati da abo bo igbeojuorun lowo (biosphere) iranka onipupagan pelu ipele osoni ojuibiloke giga, sugbon o je idoti nitosi ojuode nibi ti o ti je eso abe smog. At even higher low earth orbit altitudes atomic oxygen is a significant presence and a cause of erosion for spacecraft.[5]


Ìhùwà

Ìdìmú

Ní ìgbọ́násí àti ìfúnpá ọ̀págún, ọ́ksíjìn jẹ́ ẹ̀fúùfù aláìláwọ̀, aláìlóòórùn pẹ̀lú àfidá oníhóró O2, níbi tí àwọn átọ́mù ọ́ksíjìn méjéjì jẹ́ dídìpọ̀ lólóògùn mọ́ ara wọn pẹ̀lú ìtòpọ̀ ẹlẹ́ktrónì oníbẹta ayípo. Ìdìpọ̀ yìí ní ìtòrò ìdìpọ̀ méjì, bẹ́sìni ìjúwe rẹ̀ ṣe é pè bíi ìdìpọ̀ ẹ̀mejì[6] tàbí bíi ìsopọ̀ ìdìpọ̀ ẹlẹ́ktrónì ìkan-méjì àti two ìdìpọ̀ ẹlẹ́ktrónì méjì-mẹ́ta.[7]

Ọ́ksíjìn ìbẹta (ó yàtọ́ sí òsónì, O3) ni ipò oríilẹ̀ hóró O2.[8] Ìtòpọ̀ ẹlẹ́ktrónì hóró rẹ̀ ní ẹlẹ́ktrónì méjì alánìníkejì tí wọ́n jókòó ona-àyípo oníhóró adíbàjẹ́ méjì.[9]



Itokasi