Ata ṣọ̀mbọ̀

Ata ṣọ̀mbọ̀ tàbí (chili)[1].[2] Ata ṣọ̀mbọ̀ ni wọ́n ma ń lo láti lè jẹ́ kí ónjẹ ó ta lẹ́nu. Èròjà (Capsaicin) ni ó ma ń fún ata ṣọ̀mbọ̀ ní agbára láti ṣe iṣẹ́ títa lẹ́nu.

Young chili plants
Illustration from the Japanese agricultural encyclopedia Seikei Zusetsu (1804)

Ibi tí ṣọ̀mbọ̀ ti ṣẹ̀ wà

Ata ṣọ̀mbọ̀ lò ni ó ṣẹ̀ wá láti orílẹ̀-èdè Mẹ́síkò [3]. Ata ṣọ̀mbọ̀ lò tan kalẹ̀ àgbáyé láti ilẹ̀ Mẹ́síkò látàrí ìdòwòpọ̀. Wọ́n máa ń lò ó fún oúnjẹ sísè àti òògùn ìbílẹ̀.

Àwọn Ìtọ́kasí