Neanderthal
Neanderthal (pípè /niːˈændərtɑːl/, /niːˈændərθɔːl/), tabi /neɪˈændərtɑːl/),[1] bakanna kiko bi Neandertal,[2] ni ikan ninu iran Homo to ti pare to wa nigba Pleistocene specimens ni Europe ati apaiwoorun ati arin Asia. Neanderthals je titopo boya bi subspecies (tabi eya) awon eniyan (Homo sapiens neanderthalensis) tabi bi iru eda otooto (Homo neanderthalensis).[3] Awon traits Neanderthal-asiwaju akoko yo wa ni Europe ni bi odun 600,000–350,000 seyin.[4] Loni (ni 2010) ifihan genetiki daba ibimopapo sele pelu Homo sapiens ni bi odun 80,000 to 50,000 seyin, won si ni gbagbo pe awon eniyan isun Eurasia je bi 1% de 4% Neanderthal.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
تلارملامتالاكنلاات
هتهختتتتتتتتتتةنتن