Orílẹ̀

Orílẹ̀ jẹ́ àkójọ àwọn Orílẹ̀-èdè àti agbègbè ńlá. Àwọn orílẹ̀ tó wà lágbáyé ni Asia, Africa, North America, South America, Antarctica, Europe, àti Australia.[1]

Awon Orile Aye


Agbegbe ati piposi

OrileAgbegbe (km²)Logorun
apapo isupo ile
Piposi
2008
Logorun
apapo piposi
Kikisi
Enia ni
km²
Asia43,820,00029.5%3,879,000,00060%86.70
Africa30,370,00020.4%922,011,00014%29.30
North America24,490,00016.5%528,720,5888%21.0
South America17,840,00012.0%382,000,0006%20.8
Antarctica13,720,0009.2%1,0000.00002%0.00007
Europe10,180,0006.8%731,000,00011%69.7
Australia9,008,5005.9%32,000,0000.5%3.6

Àkójọ ilẹ̀ àwọn orílẹ̀ ni 148,647,000 km², tàbí 29.1% ilẹ̀ ayé (510,065,600 km2).

Àfiwé àwọn orílẹ̀ àgbáyé





Itokasi