Àmọ̀tẹ́kùn

Ẹranko

Fún ẹranko tí Yorùbá ńpè ní Àmọ̀tẹ́kùn, ẹ wo ojú ewé [1]

Ẹkùn
Leopard
Temporal range: Early Pleistocene to recent[2]
Fọ́tò Ẹkùn Áfríkà (P. p. pardus)
Ipò ìdasí

Vulnerable  (IUCN 3.1)[3]
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Ìjọba:Animalia (Àwọn ẹranko)
Ará:Chordata
Ẹgbẹ́:Mammalia (Àwọn afọmúbọ́mọ)
Ìtò:Ajẹran
Suborder:Ajọ-ológìnní
Ìdílé:Ẹ̀dá-ológìnní
Subfamily:Pantherinae
Ìbátan:Panthera
Irú:
P. pardus[1]
Ìfúnlórúkọ méjì
Panthera pardus[1]
(Linnaeus, 1758)
Subspecies

See text

Present and historical distribution of the leopard[3]

Ẹkùn (Panthera pardus) ni ìkan nínú àwọn irú ẹranko márùn tó wà láyé nínú ìbátan Panthera, ìkan nínú àwọn Ẹ̀dá-olóngbò.[4] Ó pọ̀ káà kiri ní agbègbè Ìsàlẹ̀-Sàhárà Áfríkà, ní àwọn agbègbè kan ní apá Ilàòrùn àti Arin Asia, ní ìsàlẹ̀orílẹ̀ India dé apá Gúúsù-ìlàòrùn àti Ìlàòrùn Asia.

Itokasi