Àìjẹ̀un-dáradára

Àìjẹ̀un-dáradára tabi aijẹ ounjẹ t'oyẹ jẹ ipo ti o n waye lara jijẹ ounjẹ ti awọn ounjẹ aṣara l'ore koto tabi ti o ti pọju ti o si fa awọn iṣoro ilera.[1][2] Awọn ounjẹ aṣara lore le jẹ́: kalori, puroteni, kabọhidireti, awọn fitamin tabi minira.[2] A saba maa n lo ni pataki lati tọkasi aijẹun to dara to nibi ti kosi kalori, puroteni tabi awọn eroja ounjẹ; sibẹsibẹ, o tun pẹlu ijẹun ju.[3][4] Bi aijẹ eroja ounjẹ to ba waye boya ni iloyun tabi ṣaaju ọmọ ọdun meji o le jasi awọn iṣoro aileyipada pẹlu idagba ifojuri ati ọpọlọ.[2] Aijẹ ohun aṣara lore to ti o gaju, ti a mọsi ifebipa, leni awọn aami ti o pẹlu: ràrá, ara gbigbẹ, ailokun ti o to, ati ẹsẹ wiwu ati ikùn.[2][3] Awọn eniyan tun saba maa n ni awọn akoran wọn si saba maa n tutù. Awọn aami ti aisi eroja inu ounjẹ to dale irufẹ eroja ounjẹ ti kosi nibẹ.[3]

Àìjẹ̀un-dáradára
Àìjẹ̀un-dáradáraRíbónì olómi ọsàn kan—akiyesi riboni fun àìjẹ̀un-dáradára naa.
Àìjẹ̀un-dáradáraRíbónì olómi ọsàn kan—akiyesi riboni fun àìjẹ̀un-dáradára naa.
Ríbónì olómi ọsàn kan—akiyesi riboni fun àìjẹ̀un-dáradára naa.
Ìpínsọ́wọ̀ àti àwọn òkunfà ìta
ICD/CIM-9263.9 263.9
MedlinePlus000404

Aijẹ ounjẹ toyẹ maa n waye nitori airi ojulowo ounjẹ jẹ.[5] Eyi ko sai somọ ọwọn gogo iye ounjẹ ati iṣẹ.[2][5] Aisi ti ifun lọ́mú le dakun, bi awọn ọpọ awọn akoran arun bii: inu wiwu, arun ẹdọforo, ba ati eeyì ti o maa n ṣafikun awọn eroja ounjẹ .[5] Awọn oriṣi aijẹun toyẹ to meji lowa: aijẹ ounjẹ toyẹ okun- puroteni ati alebu aijẹ ounjẹ to.[4] Aijẹ ounjẹ toyẹ okun- puroteni ni awọn alebu meji: marasmus (aini puroteni ati kalori) ati kwashiorkor (aito puroteni nikan).[3] Aini eroja ounjẹ toye ni: aini ayọnu, ayodini ati fitamini A.[3] Lakoko oyun, ti o da lori ibeere-fun pupọ, awọn aito wa wọpọ si.[6] Ni awọn ọkan awọn orilẹ-ede ti o n dagba ounjẹ ajẹju bii isanraju ti wa n pọ ni aarin awọn awujọ bii aijẹ ounjẹ to.[7] Awọn okunfa aijẹun toyẹ to miiran ni iri ara-ẹni bi pe a sanra nigba ti a ru àti bṣẹ abẹ idin ounjẹ ti inu le gba kù[8][9] Laarin awọn agba aijẹ ounjẹ to'yẹ wọpọ nitori okunfa afojuri, ero inu ati ibalopọ.[10]

Ipa lati mu gbooro ounjẹ jẹ lara awọn ipo ti o ya iranwọ idagba.[11] Ifun lọmu le din iye aijẹ ounjẹ to ati iku ninu awọn ọmọde ku,[2] ati awọn ipa lati mu gberu iṣe bẹẹ dagba pọ.[12] Ninu awọn ọmọde pipese ounjẹ pẹlu ọmu-mimu laarin oṣu mẹfa ati ọdun meji mu abajade gberu.[12] Ẹri gidi wa ti o kin lẹhin pe eroja ounjẹ ti ọpọ awọn eroja ounjẹ lakoko oyun ati laarin awọn ọmọde ni awọn orilẹ-ede ti o n dagba.[12] Lati pese ounjẹ fun awọn ti o nilo rẹ ju ni ipese ounjẹ ati ipese owo ki awọn eniyan le ra ounjẹ laarin ọja ilu lọ geere.[11][13] Fifun awọn eniyan lounjẹ nikan to.[11] Ibojuto aijẹ ounjẹ t'oyẹ ti o l'ewu laarin ile eniyan pẹlu àwọn ounjẹ ìlo iwosan aarun ṣeeṣe lọpọ igba.[12] Laarin awọn ti o ni ewu aije ounjẹ toyẹ lowọ awọn iṣoro itọju ilera miiran laarin ile-iwosan ni a bọwọlu.[12] Eyi nilo abojuto aito ṣuga, imọlara ara, ara-gbigbẹ, ati ifun-lounjẹ diẹdiẹ.[12][14] Igbesẹ awọn ogun aṣodi si akoran ni a bọwọlu nitori akoran ti o pọ.[14] Awọn ilana itọju ọjọ pipẹ ni: imugbooro awọn iṣe agbẹ,[15] re dioṣi kuim, imumọtoto gbooroth, atiofifun awọn obinrin ni agbara iṣẹ[11]

Awọn 925 miliọnu eniyan ti kori ounjẹ jẹ to ni agbaye ni o wa ni 2010, ọpọ ti 80 miliọnu lati 1990.[16][17] Awọn eniyan biliọnu ti a ka miiran ti koni fitamin ati eroja ounjẹ toyẹ.[11] Ni 2010 aijẹ ounjẹ toyẹ ti agbara puroteni ti ṣokunfa awọn iku bii 600,000 de 883,000 awọn iku ni 1990.[18] Awọn aito ounjẹ toyẹ aito ayodini ati arun aito ayodini, fa iku 84,000 miiran.[18] Airi ounjẹ toyẹ jẹ ni 2010 n okunfa 1.4% gbogbo ailera igbe-aye ti a sun.[11][19] Bi ida mẹta awọn iku laarin awọn ọmọde ni a gbagbọ pe airi ounjẹ jẹ to lofa; sibẹsibẹ, ako sọ awọn iku naa bẹẹ.[5] Ni 2010 a ṣakojọ pe o ṣokunfa bii 1.5 miliọnu awọn iku awọn obinrin ati ọmọde[20] awọn kan tilẹ sọpe iye naa le ju 3 miliọnu.[12] Ati afikun 165 miliọnu awọn ọmọde ni aidagba bi-o-tiyẹ lara arun naa.[12] Airijẹ to wọpọ ni awọn orilẹ-ede ti o n dagba.[21]

Awọn Itọkasi