Alákàn

Taxonomy not available for Brachyura; please create it automated assistant

Alákàn tàbí Akàn tí wọ́n ń dà pè ní decapod ní èdè Gẹ̀ẹ́sì jẹ́ ẹranko tí ó lè gbé lórí ilẹ̀ àti inú omí. (Gíríkì: βραχύς = short,[2] οὐρά / οura = tail[3])Ẹranko yí ma ń gbé nínú pàlà pálá ihò ilẹ̀ tàbí abẹ́ àwọn ewéko ní etí omi. Bákan náà ni kò sí ibi tí wọn kò sí ní orílẹ̀ àgbáyé pátá.

Crab
Temporal range: Jurassic–Recent
Grey swimming crab
Liocarcinus vernalis
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ]
Sections and subsections[1]
  • Dromiacea
  • Raninoida
  • Cyclodorippoida
  • Eubrachyura
    • Heterotremata
    • Thoracotremata
Ilé Alákàn

Ìrísí rẹ̀

Alákàn jẹ́ ẹranko tí gbogbo egungun ara rẹ̀ wà ní ìta tí àwọn ẹran rẹ̀ sì sá pamọ́ sí inú ihò egungun ara rẹ̀. Ó sábà ma ń ní ẹsẹ̀ mẹ́fà; mẹ́ta lọ́tùn ún mẹ́ta lósì, bẹ́ẹ̀ ni ó ní kiní kan bí ìlédìí kọ̀kan lọ́tún àti lósì, tí ó sì tún ní ọwọ́ méjì níwájú tí ọwọ́ náà sì tún ní ẹ̀mú (pincer) tí ó fi ma ń dáàbò bo ara rẹ̀ lọ́wọ́ ewu.

Oríṣi Akàn tó wà

Oríṣríṣi akàn tí ó wà ni ó ní orúkọ tí wọ́n ń oè wọ́n ní agbègbè tí wọ́n bá wà ní orílẹ̀ àgbáyé. Lára orúkọ àti oríṣi akàn tí ó wà ni:

  • Akàn gbògbó
  • Akàn Òkun
  • Akàn Ọ̀sà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ

Àwọn Ìtọ́ka sí