Luiz Inácio Lula da Silva

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Brazil

Luiz Inácio Lula da Silva (Pípè ni Potogí: [luˈis iˈnäsjʊ ˈlulɐ dä ˈsiʊ̯vɐ]; ojoibi 27 October 1945), o gbajumo gege bi Lula,[2] ni Aare orile-ede Brazil lati 2003 titi 2011. A tún yàn sípò ààrẹ fún sáà kẹta ni odun 2022, tí à sì ṣe ìbúra-wọlé fun ní ọjọ́ kínní oṣù kínní ọdún 2023. Oun ni Ààrẹ orílè-èdè Brazil lọ́wọ́ lọ́wọ́.

Luiz Inácio Lula da Silva
Portrait of Luiz Inácio Lula da Silva
35th President of Brazil
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
1 January 2023
Vice PresidentGeraldo Alckmin
AsíwájúJair Bolsonaro
In office
1 January 2003 – 1 January 2011
Vice PresidentJosé Alencar
AsíwájúFernando Henrique Cardoso
Arọ́pòDilma Rousseff
Leader of the Workers' Party
In office
10 February 1980 – 15 November 1994
AsíwájúPosition established
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí27 Oṣù Kẹ̀wá 1945 (1945-10-27) (ọmọ ọdún 78)
Caetés, Brazil
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPartido dos Trabalhadores (PT)
(Àwọn) olólùfẹ́Maria de Lurdes (1969-1971; Deceased)
Marisa Letícia Rocco Casa (1974-2017)
Rosângela Lula da Silva (2022-)
Àwọn ọmọFábio Luís
Lurian Cordeiro
Luís Cláudio
Marcos Cláudio (Adopted)
Sandro Luís
ResidenceSão Bernardo do Campo
ProfessionAutomotive worker
Union organizer
SignatureLula (Signature of Luiz Inácio Lula da Silva)

Itokasi