Àgbàdo

Odun,aleseje,ale fi se ogi fun eko mimu

Àgbàdo (Látìnì: Zea mays) ni ó jẹ́ óuńjẹ jij́ẹ oní hóró tí àwọn ènìyàn ilẹ̀ apá Gúúsù ilẹ̀ Mexico ṣe àwárí rẹ̀ ní ǹkan bíi egberun mewa odun seýin..[1][2][3][4] Igi àgbàdo ma ń yọ ewé sooro, tí ó sì ma ń yọ ìrùkẹ̀rẹ̀ ní ọwọ́ òkè èyí tí ó ma ń ṣe atọ́nà fún yíyọ ọmọ àgbàdo[5][6] . Àwọn onímọ̀ sáyẹ́nsì fẹ́ràn láti máa pèé ní Maize (àgbàdo) nítorí wípé orúkọ yí ni ó gbajúmọ̀ jùlọ fún irúfẹ Oúnjẹ oníhóró yí, tí ó sì ní it̀umọ̀ oríṣiríṣi lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn ní orílẹ̀ àgbáyé.

Àgbàdo
Illustration showing male and female maize flowers
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Ìjọba:Ọ̀gbìn
Clade:Vascular plant
Clade:Flowering plant
Clade:Monocotyledon
Clade:Commelinids
Ìtò:Poales
Ìdílé:Poaceae
Ìbátan:Zea (plant)
Irú:
Z. mays
Ìfúnlórúkọ méjì
Zea mays
Zea mays "fraise"
Zea mays "Oaxacan Green"
Zea mays "Ottofile giallo Tortonese”



Itokasi