Àrún èrànkòrónà ọdún 2019

Àrùn èrànkòrónà ọdún 2019 (tàbí ní èdè gẹ̀ẹ́sì bíi Coronavirus disease 2019, COVID-19) jẹ́ àrún àkóràn kan tí èràn àrọ́lù àìsàn ìmín olóró gbígboró, èràn kòrónà irú 2 (SARS-CoV-2) ń mú wá.[1] Àrùn náà kọ́kọ́ jẹ́ dídámọ̀ ní December 2019 ní Wuhan, ní China, tó sì ti ràn ká gbogbo àgbáyé láti ìgbà náà pẹ̀lú ajakale-arun kaakiriaye erankorona odun 2019-2020.[2][3] Nínú àwọn ami-aisan rẹ̀ tó wọ́pọ̀ ni iba, ikọ́, àti àìlèmín balẹ̀. Àwọn àmì àìsàn míràn tún lè jẹ́ irora, híha kelebe, igbe olomi, ikanra ona-ofun, ainlegbo oorun, ati irora ikun.[4] Botileje pe opo alaisan arun yi ni ami-aisan to loworo, awon miran le ni eran edo ati ikuna patapata opolopo ifun-ara.[5] Titi di ojo 3 April 2020, iye awon alaisan COVID-19 ti a mo lagbaye je 1,040,000, iye awon alaisi je 55,100 deaths.Iye awon ti ara won ti ya je 221,000.

Àrún èrànkòrónà ọdún 2019 (COVID-19)
Symptoms of COVID-19Àrún èrànkòrónà ọdún 2019 (COVID-19)
Symptoms of COVID-19Àrún èrànkòrónà ọdún 2019 (COVID-19)
Symptoms of COVID-19
Ìpínsọ́wọ̀ àti àwọn òkunfà ìta

Àwọn Ìtọ́kasí

Drink green tea, take Vitamin C, turmeric, ginger and elderberry, eat oranges, fruits and vegetables. Use hand sanitizer and wear mask on airplane.