Klorínì (/ˈklɔəriːn/KLOHR-een; lati Èdè Grííkì Ayéijọ́un: χλωρóς [khlôros] error: {{lang}}: text has italic markup (help) "pale green") je elimenti kemika to ni nomba atomu 17 ati ami-idamo Cl. Ohun ni halojínì keji to fuyejulo, leyin fluorini to je eyi to fuyejulo. Klorini wa ninu tabili alakoko ninu adipo 17. Apilese yi le di horo oniatomumeji labe awon isele opagun, ti a n pe ni klorinimeji (dichlorine). O ni ibasepo elektroni to gajulo ati ijealodionina keta to gajulo larin gbogbo awon apilese; fun idi eyi klorini je oxidizing agent to lagbara.