Ibi Ọ̀ṣọ́ Àgbáyé

Ibi Ọ̀ṣọ́ Àgbáyé UNESCO je ibi (bi egan, okeile, adagun, asale, iboji, ileigbe, complex, tabi ilu) to wa ninu akojo ti Eto Oso Agbaye akariaye se ti Igbimo Oso Agbaye UNESCO unsedari, to ni awon orile-ede 21 gege bi omo egbe[1] ti won je didiboyan latowo Ile-igbimo Gbogbogboo fun igba odun- merin kan.[2]Ibi Oso Aye je ibi to se pataki fun asa tabi nitori boseri.

Logo of the UNESCO World Heritage Committee



Itokasi