Èdè Azerbaijani

Èdè Azerbaijani

Azerbaijani
Azərbaycan dili (Latin script)
Азәрбајҹан дили (Cyrillic script)
آذربایجان دیلی (Perso-Arabic script)
Ìpè/azærbajdʒan dili/
Sísọ ní Iran,
 Azerbaijan
 Georgia,
 Jẹ́mánì
 Russia,
 Estonia
 UK
 USA
 Uzbekistan
 Syria
 Iraq[1],
 Turkey,
 Turkmenistan
 Ukraine,
 Canada
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀20-31 million [2][3][4][5][6][7]
Èdè ìbátan
Altaic[8] (controversial)
  • Turkic
    • Oghuz
      • Azerbaijani
Sístẹ́mù ìkọLatin alphabet for North Azeri in Azerbaijan, Perso-Arabic script for South Azeri in Iran, and, formerly, Cyrillic alphabet for North Azeri (Azerbaijani variants)
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Àkóso lọ́wọ́Kòsí àkóso oníbiṣẹ́
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1az
ISO 639-2aze
ISO 639-3variously:
aze – Azerbaijani (generic)
azj – North Azerbaijani
azb – South Azerbaijani

Ọmọ ẹgbẹ́ ni èdè yìí jẹ́ fún ẹgbẹ́ èdè tí a ń pè ní Turkic. Ẹgbẹ́ èdè Turkic yìí jẹ́ ọmọ ẹbí Altaic. Àwọn tí ó ń sọ Azerbaijani tó mílíọ̀nù mẹ́rìnlá ní Azerbaijan ní ibi tí wọ́n ti ń lò ó gẹ́gẹ́ bí èdè ìṣe ìjọbi. Wọ́n tún ń sọ èdè yìí ní Turkey, Syria àti Afgloanistan. Wọ́n tún máa ń pe èdè yìí ni Azeri. Àkọtọ́ Cyrillic ni wọ́n fi ń kọ ọ́ sílẹ̀ ní Azerbaijan ṣùgbọ́n àkọtọ́ Arabic ni wọ́n fi ń kọ ọ́ sílẹ̀ ní Iran. Wọ́n fi ojú èdá èdè pín wọn sí Swuthern Azerbaijani) àti Northern Azerbaijani tí mílíọ̀nù méje ènìyàn ń sọ.



Itokasi