Èrànkòrónà

Àwọn ẹ̀rànkòrónà jẹ́ àwọn èràn tọ́ ń kó àrùn ran àwọn ẹranko afọ́mọlọ́yàn bíi ènìyàn, àti àwọn ẹyẹ. Bí ó bá jẹ́ ènìyàn, Coronavirus tàbí Koronafáírọ́ọ̀sì yìí a máa fa àrùn sí àwọn ẹ̀yà ara inú tí ènìyàn fi ń mí, tí ó sìn lè pànìyàn kíákíá. Ó lè fa irú àrùn yìí tàbí ìgbẹ́-gbuuru (diarrhea) fún ẹyẹ, Ẹlẹ́dẹ̀ tàbí Màlúù. Lọ́wólọ́wọ́ báyìí kò sí ẹ̀rọ̀ tàbí oògùn ìwòsàn tàbí Ìdènà tí ó lè wo àrùn tí Coronavirus yìí máa ń fà. [4][5]

Orthocoronavirinae
Electron micrograph of coronavirus virions
Ìṣètò ẹ̀ràn [ e ]
(unranked):Èràn
Realm:Riboviria
Ará:Incertae sedis
Ìtò:Nidovirales
Ìdílé:Coronaviridae
Subfamily:Orthocoronavirinae
Genera[1]
  • Alphacoronavirus
  • Betacoronavirus
  • Deltacoronavirus
  • Gammacoronavirus
Synonyms[2][3]
  • Coronavirinae

Àwọn Ìtọ́kasí